Moberu Olorun, available in both Yoruba and English Language

Yoruba

Ìwé tuntun “Moberu Ọlọrun” jẹ́ ìtàn ìmúlò àti ìjìnlẹ̀ ìmọ̀ tó ń fi hàn pé ìbẹ̀ru Ọlọrun ni ìpilẹ̀ ọgbọ́n. Ìwé yìí yóò mú kó ye wa pé ìbẹ̀ru Kristi kì í dá lórí ìbànújẹ, ṣùgbọ́n ó dá lórí ìfẹ́ àti ìgbọràn. Kí ìwé yìí ràn ọ́ lọ́wọ́ láti gbé ìgbésí ayé tí ń fi ògo Ọlọrun hàn nínu Ogun gbogbo.

English 

The book “I Fear God” reveals the true meaning of the fear of God—founded not in terror but in love, wisdom, and obedience to Christ. It is a call to live a life that reflects holiness, reverence, and the beauty of walking faithfully with God.