Yoruba
Ìwé tuntun Aworan Tani Iwọ'Ṣe? ń béèrè ìbéèrè tó lágbára jù lọ nípa ìdánimọ̀ wa gẹ́gẹ́ bí ọmọ ènìyàn. Ìdáhùn yi ni a rí nínú Kristi—Ẹni tí a dá sí àwòrán Rẹ̀. Ìwé yìí yóò fi ọ́ hàn gẹ́gẹ́ bí àfihàn pipe ti Kristi.
English
The book Whose Image Are You? confronts the most vital question of identity. The answer is found in Christ—we were created in His image and likeness. This book helps you discover yourself as the true reflection of Christ.